BlueGlobe International
My status

Translation Services

Translation Services

Career With BlueGlobe

Banner
Banner
Banner

SAIC

"SAIC is a FORTUNE 500® scientific, engineering, and technology applications company that uses its deep domain knowledge to solve problems of vital importance to the nation and the world, in national security, energy and the environment, critical infrastructure, and health. BlueGlobe International LLC consistently provides language services on a global scale which meet the strict vendor standards required by SAIC."


Fulbright

"BlueGlobe cares .. our expectations were exceeded with accuracy and promptness. A long term relationship will benefit our firm and yours."


Crowell-moring

"Thanks again for extra-ordrinary services."


AAAS

"Friendly staff combined with unusual promptness and services will see our association always requesting BlueGlobe."

* For Translation - click flag

Itumo lede Yoruba

Youruba

Ile Ise wa Blue Globe International n pese ogbufo to pegede lati ede geesi si ede yoruba

A n’ pese itumo to se regi to si see gbarale lati ede geesi si ede Yoruba, awon osise wa je ogbonkangi ninu ijinle imo geesi ati Yoruba. Awon osise ti won n ba wa tumo lati ede geesi si ede Yoruba gbosasa, won ni iriri, won si je akekoo tio kekoo yanju, A lepese itumo fun oniruuru eda iwe yala itumo lati ori ero isofunni intaneti, iimeeli, leta, iwe pelebe, iwe isegun, iwe ero, iwe sayensei ati orisirisi iwe loniruuru, Siwaju sii, A , tun pese itumo lati oniruuru ijinle eka imo eko, yala, iwe ofin, iwe isowo, iwe isegun, iwe eko sayensi, onimo ero, iwe eko itaja, ati bee bee lo. Lati rii daju wipe a pese itumo to gun rege, Ile ise wa BlueGlobe rii daju wipe omo bibi ile Yoruba to gbo sasa to si kawe dunju ni yoo se itumo eyikeyi lati ede geesi si ede Yoruba. Awon ogbufo ti o n’ sise pelu wa ni iriri fun opolopo odun won si je ogbosasa ni oniruuru eka imo eko.Won si ni imo ti o gun rege lati tumo ede lona to yanju to si pegede.

Ki lo mu ile ise wa Globe International yato?

Aseyori ti an ri gba lati inu ise wa je wa logun pupo igboriyin lati odo awon eniyan si n fun wa lokun lati tesiwaju! Gege bi ile ise ti oni oniruuru eka bii (ogbufo,itunmo, idako, ati bee bee lo.), A n bojuto orisirisi ojuse lagbaye fun oniruuru eniyan, eka ile-ise ati bee bee lo. Ki a le pese ogbufo ti o pegede ti o si gun rege, a seto lati ri sii pe an boju to itoleese oniruuru itumo ni oniruuru apa eka bi itumo naa se n lo lowo. A fe ki awon awujo ti an ba dowopo ni ibale okan, ki ise wa si tewon lorun, ohun ti o je wa logun ju si ni ki ise wa tewon lorun ki won sile jerii si lodo awon elomiiran.

 • Pataki Awọn ede kariaye bi ọgọrun 100
 • Ogbufo lo niruuru eka
 • Owo ti o won niwon ba
 • Ise ti o gbamuse
 • O ni bara ti osee fokan tan
 • Ile-ise ogbufo ti ose gbara le julo ni agbaye
 • Ogbufo lona ogurun ede loniruuru ona
 • Ajosepo lati odo awon osise ti o mose nise ti osi dangajia
 • A wa laroowoto yin ni igba bogbo,Gbogbo ojo losee

Itoleese ise mewaa ti ile ise wa n bojuto

FItoleseese yii loniruuru ona mewaa yoo fi dayin loju ona pipeye tia gba n lo lati tumo ede loniruuru ede si ede yoruba:

 1. Ogbufo eyikeyii si ede Yoruba ni a gbeyewo lati odo aare ti on bojuto ile-.ise translation
 2. Itoleese ogbufo ti o peye ti o siwa letoleto ni ao dari lati odo aare ile-ise wa
 3. TIse ogbufo ti a ti se pari ni a oodari sodo ogbufo ti o kekoo yege ti osi dangajia.
 4. Apo Ero atumo ede ni a oo lo fun eru-ise naa
 5. Ero CAT ni a oo lo lati rii daju wipe ogbufo naa peye osi gbamuse
 6. Ogbufo naa ni a oo tumo si ede Hausa
 7. QEto ayewo ti o peye ti osi see gbarale ni a oolo lati fi bojuto ise naa
 8. TIse ogbufo ti a ti se pari ni a maafi sinu ero (DTP)
 9. Ogbufo naa ni a oo gbeyewo lekeeji ni kikun ati lona ti o tubo peye lati owo omo bibi ile yoruba
 10. Ayewo ti keyin ni aare ile.ise wa yoo gbe yewo pelu iranlowo ogbufo ti o laami laaka – A oo fi ise na jise

OAwon osise wa ti won je oniriiri, ti won ja fafa, ti won si nimo ti o kun yoo rii daju wipe ise naa ni a fi jise ni kia mosa ni iwonba akoko ti a seleri fun won . Laika ede ti a fe tu si ede Yoruba pe,yala (Yoruba si Geesi (Ile amerika), English (Ile amerika) si Yoruba), tabi ede alapapoo miiran (Faranse si Arabic, Portugali (Brazil) si Spanish (Spain), ati bee bee lo.), Iyi ise yin ati idunnu yin je wa logun, osi fiwa lokan bale ni BlueGlobe International.

Iye ti a n gba – Ede Yoruba

Opolopo koko ni a oo gbeyewo lati fenu ko lori iye ti a oo gba (iye leta, gongo ojo ti ise gbodo pari, iye gbolohun, itoleese eto ise naa, ati beebee lo.) gbogbo awon koko yii ni a oo gbeyewo tati fenu ko lori iye ti a oo gba fun ise yin. Lati le mo daju iye ti e oo san, E beere fun ninu foomu 'Request a quote' ki esi fi isofunni yin ni kikun sinu foomu naa. Koko ti ise naa dale lori ni a le rigba yala loju ewe intaneeti, tabi ona eyikeyii ti o ba teyin lorun, ki esi je ki a mo iye ti e fe san fun ise naa lai fi ohunkohun pamo fun wa.

ile-ise wa BlueGlobe International wa laroowoto yin nigba gbogbo, wakati merinlelogun loojo ati ojo meeje lose! Awon osise wa ti won je omoluwabi ti ara won si yo mo eeyan yoo setan lati ran yin lowo nigba gbogbo ati lona eyikeyii.

Oludari ero ibanisoro:
Ede Geesi
+1.541.330.0450 (USA)

E le kan siwa lori ero intaneeti nigba gbogbo (24/7) offered in:
Ede Gẹẹsi - Ede Rọsia - Ede Speeni - Ede Ṣaina - Ede Faranse - Ede Jepaanu
This e-mail address is being protected from spambots. You need JavaScript enabled to view it

Abo isofuunni

Bibowo fun isofunni yin ati pipaa mo je ile-ise wa BlueGlobe International logun pupo.Ise eyikeyii ti a ba rigba lati odo yin, yala leta, iwe isofunni, iwe apamo tabi iwe ofin ati bee be lo, a maari daju wipe isofunni eyikeyii ti o wa nibe ni a pamo ti a si daboobo lona ti yoo fi iyin fun ise wa.. Gongo wa lati igba de igba ni lati rii daju wipe, okan awon ti won n bawa dowopo bale won si gbonka le wa. Jowo be oju ewe adiresi wa wo lori ero intaneeti ki osi gbe eri ti o fihan pe abowo fun isofunni eyikeyii ti a barigba yewo. Oju ewe yii yoo se alaye ni kikun iru isofunni ti a n rigba, bi a se n lo won ati bi a se n pawon mo . Jowo a roo lati farabale gbe e yewo. Gbe eri ti ofihan pe a bikita fun isofunni yin yewo lati loye ni kikun nipa bi a se bikita fun isofunni , a kii tu idi kulekule isofunni yin han fun enikeni tabi ile-ise, bo ti leje wipe, e le ma loye kulekule koko yii daadaa, Sugbon labe ofin ile eyikeyii, a mo idi ti ofi se Pataki to lati pa isofunni enikeni mo daadaa, a si maa n rii daju wipe a daabobo isofunni eyikeyii tabi ise eyikeyii ti a ba rigba lati odo yin, Eyi si ti fi ise yin ile-ise wa Blue Globe International.

Itumo si Oruko Yin

Contact Us Nje o n wa ise?

Nje o ni ebun ede yala ebun ede kiko tabi ede siso? Bi o bar ii bee, a roo lati buwo lu foomu wa to wa loju ewe yii, kii yoo naa lowo, ko si ni na e ni akoko.

Contact Us Alamọdaju Kika ati fifamisi awọn atunṣe!

Nje oni iririlenu ise ogbufo osi kekoo yege ninu ede yoruba ? Se o kawe yanju os I je ogbonkangi ninu ede Yoruba kiko ati girama? O le darapo mo awon osise wa ni Blue Globe International!

Contact Us Eka ise

Ni Ile-ise wa BlueGlobe International, ise wa kii ku die kaato, A maan sapa lati mu ipo akoko nidi ohunkohun ti a ba se. ojulowo ise ti ose gbarale ti ko labawon ni a si maan n se f’awon awujo ti o bawa dowopo. Awon ti won siti bawa dowopo teleri maan polongo ise wa faraye gbo, ise wa lo n soro kii se oro enu wa.

Contact Us E kan si wa

Opolopo Orile-ise l’agbaye lo fokan tan wa -
... laipe eyin pelu yoo gbo’se wa wo

Telefon:
+1.541.330.0450
+55.21.2262.1793
+91.172.2561020
Mobil:
+1.541.213.8526
+55.21.2262.1793
+91.981.4535577
Fax (USA-Argentina-India):
+1.541.330.0451
+55.21.2262.1793
+91.172.2561020

www.blueglobetranslations.com

Eka Ogbufo -
… ni awọn ede bi ọgọrun 100

Ede Larubawa Ede Ebeeru
Ede Ṣaina Ede Itali
Ede Dọọṣi Ede Jepaanu
Ede Gẹẹsi Ede Latini
Ede Faranse Ede Pọtugaali
Ede Jamani Ede Rọsia
Ede Giriki Ede Speeni
Gbogbo Awọn ede

Professional Translation Services Company

Request a Quote

 

feed-image Feed Entries

Get your FREE QUOTE now or call us directly at 1.541.330.0450 or 541.213.8526 (USA)